Munbari Agbaye


4.8 ( 4738 ratings )
Onderwijs Boeken
Developer: fada media
1.99 USD

Irori eto
Kikojo ati kiko sile awon agboye esin Islam ti o pataki eleyi ti imudogongo ati ifiko awon al-Ummah re je dandan ni awon onka ede ninu awon ede ti o nsemi, ati fifon kaakiri .
Leta
Kiko awon agboye Islam ti o pataki jo ati imunde ogongo re pelu gbogbo ilana ti o rorun ni didara ti o ga .
Awon erongba
Gbigbe ilana ipepe kale pelu awon ede .
Kikoni ni eko Islam ati tan kaakiri aye .
Fifon ilana awon Ahlus suna wal Jamaha .
Sise afihan idanto khutuba sise ni Agbaye esin Islam .
Gbigbe awon ti won ni ero atisise ipepe si inu iroyin tuntun.
Mimu eleyi ti o ba rorun ninu awon ilana ipepe si oju ona Olohun sise pelu awon ede .
Awon a se jade eto
Ogota khutuba ti o je ti ilana awokose
Ogota ohun ti a le tetigbo
Ogota ijoko muhunmaworan
Ile tiira eko ti o kun keke
Awon irinse ti o ha nkan
Awon ede eto
Ede Faranse
Ede Rossia
Esde Indonesia
Ede Faarisi
Ede Bangaliyah
Ede Urdu
Ede Yoruba
Ede Sawahiliya
Ede China
Ede Burtigaliya
Portugués
Ede Hausa
Ede Asbaniya
Ede Tojiikiya
Awon esa ti o wa fun eto
Ere ti o ga ti ijiro inawo ati asiko
Lilo ti o je ti ilana lati ara ibasepo ti o wa laarin iroyin ati ipepe
Abala ti a ko ni ise ati eto inawo
Irorun ti o wa nibi ipolowo
Afikun ipepe je oranyan nitori wipe a o maa mo awon ohun ti o wa leyin re lee.
"Titi ti ike yio fi de odo gbo eniyan pata"
"A kii ran ojise kan ni ise ayaafi pelu ahon awon ijo re lati le maa se alaye fun won" [ Ibrahim vs 4]